Owo tuntun kan, iye agbe kan, iye aluko kan, ikode
kan, monu
die, odindin atare kan, ewe ola lopo die.
Sise re: Ao fi owo
tuntun yen we gbogbo nkan wonyi bii cigar yato si Ewe ola ati
atare, ao fi owo naa sinu ape, ao fi atare si legbe, ao wa da ewe
ola bo Lori ti yio bo daada, ao jo po daada, ao da ebu na sinu
schnapp ati peak milk.
Lilo re: Ao maa jin po mu laro laro
pelu opolopo adura.