OKIGBE IGI TODAJU FOR PROTECTION

OKIGBE IGI TODAJU
Eyin igba ijapa, odindi atare kan, apola igi, ao bu die lara re,
ao jo ninu ikoko titun ni ihoho...
Lilo Re... Ao duro lori odo, ao singbere meje sori, meje is aya, meje
si eyin, ao sin meta si all joint ara wa... gbogbo igi ti won ba
lamon wa koni wole, yio si da sonu.