ATUDE TODAJU FOR VICTORY AND DELIVERANCE

Atude todaju

Kere owu topo bi kongo kan , eru awonka ao jo ao ma fi foko mu taba fe fun eyan ao
ba pe ofore si toba jepe awa ni ao pe fun ra wa taba jo tan ao ro sibi kan ao te ni ifa osa meji

Ofore
Atidi soro 3*, atobo muje 3*, atidi sakin 3*, awon ni won difa fun awon eleye,
ni ojo ti won ti ikole orun bowa si ikole aye won pade igba irunmole lona, won ni ki
awon igba irunmole fi aye han awon igba irunmole ni kini won fe lo se nile aye won
ni awon fe lo mapa awon omo eniyan je bi eran awon fe lo ma tilekun ola ati ilekun
arisiki, awon igba irunmole ni toba ribe awon koni fi ona ile aye han won , won rin
siwaju die won pade orunminla lorita merindinlogun won ni iwo orunminla fi ona ile
aye han awon, orunminla ni kini won fe lo se won ko won ro gbogbo ibi ise owo won
, orunminla ni toba ribe ohun koni fi ona ile aye han won won ni awon mafun
orunminla ni nkan imule , orunminla ni kini nkan imule na , won ni kowa kere owu ati
eru awonka kojo kowa teni odu imule , orunminla ni kini odu imule na, won ni osa
meji osa eleye kowa mawi ohun ajo wi yi si , awon eleye ki fi osu loalaloran , awon
eleye ni odi ase , awon eleye won ni odi oro ase , awon eleye won ki gboju ka alaloran
, awon eleye won ki gba ona eburu wole , orunminla ni odi oro ase, eniti a ba be Ninu
yin tio ba gbo toba lonfi osu loalaloran nko, won ni afi apa se , orunminla ni odi oro
ase, orunminla ni eniti a ba be Ninu yin tio ba gbo to lon gboju ka ile ajo nko, won ni
afi ese mejeji se, orunminla ni odi oro ase orunminla ni gbogbo eniti a ba be Ninu yin
tio ba gbo nko , won ni afi gbogbo ara run wonmuwomun, ito kan koni bale ko tun
pada senu, ki ewa sina funmi bayi bayi , gbogbo aseyori ti e ba timo emi L omo L ki
esi bayi kiakia , ao wa se adura si ao wo da sinu eko ao wa fomu �